top of page

Oríkí Òrúnmìlà

IBA ÒRÚNMÌLÀ

ÒRÚNMÌLÀ IBA O O,

ÒRÚNMÌLÀ, ELERI IPIN, AJEJU OOGUN,

ADUNDUN LAWO,

IFÁ MO PE, ELA MO PE,

IFÁ, SOWO DEERE GBOBI RE,

IYEROSUN NI ÒRÚNMÌLÀ NJE,

EKU MEKI, EJA MEJI NINU OBE RE,

IFÁ FUN WA LOMO SI,

JEKI A LÓWÓ LÓWÓ, KI A BIMO O,

KI ILE WA YIÍ, KI ATUN KI DAADAA,

ORUN LO MO ENITI YIO LA,

A SE AIYE, SE ORUN,

ELEERIN IIPIN, AJE-JU-OOGUN,

IWO LALAWOYE O,

BAMI WO OMO TEMI YE,

AJE, WOLE MI, OLA JOKO TIMI,

ORUNMILA O WA TO GEE,

KI O MOWO IWARA MI KO MI,

ÒRÚNMÌLÀ IFÁ OLOKUN, ASORAN DAYO,

OLOORE AIKU JE JOOGUN,

IREE MI GBOGBO NI WARA,

NI WARA.

ASÉ OLÓDÙMARÈ

OLÓDÙMARÈ ASÉ.


Tradução:

Òrúnmìlà eu te saúdo.

Òrúnmìlà, testemunho do destino, que tem mais eficácia do que medicina,

Pessoa de pele limpa,

Ifá eu te chamo, Ela eu te chamo,

Ifá abre as suas mãos para aceitar meu obí de oferenda.

Òrúnmìlà, você como Iyerosun, Dois ratos, dois peixes na sua sopa,

Ifá deixa prosperarmos mais filhos,

Deixa reconstruirmos nossas casas da melhor maneira.

Só o céu quem sabe quem será salvo,

Pessoa que vive no universo e no Céu,

Pessoa que é testemunha do destino e Pessoa que é mais eficácia do que a medicina,

Só você quem pode dar a vida para as pessoas;

Dê vida aos meus filhos,

Prosperidade entra na minha casa, honra senta comigo,

Òrúnmìlà, é hora de você me dar riqueza,

Òrúnmìlà Ifá, o dono do mar, que desvia fortuna para a alegria,

Traga todas as minhas fortunas depressa.

Asé do Senhor Supremo

Benção do Senhor Supremo.

204 visualizações0 comentário

Posts recentes

Ver tudo

Oríkí Osanyin

Agbénigi, òròmodìe abìdi sónsó Esinsin abedo kínníkínni; Kòògo egbòrò irín Aképè nigbà òràn kò sunwòn Tíotio tin, ó gbà aso òkùnrùn ta...

Oríkí Obàtálá

Iba òrìsà-nlá Oseremagbo Òrìsà-nla, òrìsà-nia, oba patapata Tu ba won gbe ni ode Iranje, Òrìsà-nla, ogirigbanigbo, alaye ti won...

Oríkí Egungun

Iba Egungun Ile Ile Mope O O, Akisale Mo Pe O O, Etigbure Mo Pe O O, Asa Mo Pe O O, Eti Were Ni Ti Ekute Ile, Asunmaparada Ni Tigi Aja...

Comments


bottom of page