top of page

Oríkí Yemonjá

Atualizado: 1 de set. de 2021

Iba Yeye Omo Eja

Yemonja Ooo,

Wa Gbo Ebe Mi,

Iwo Ti Nfun Eniti Nwa Omo Ni Omo,

Jowo Mo Pe O, Fun Mi Ni Omo,

So Mi Di Oloro,

Yomonjá, Yeye Awon Eja,

Fi Abo Re Bo Mi,

Ki Iku Ati Arun Ma Wole

To Mi Wa.

Iya Mi, Jowo So Ekun Mi Dayo

Asé Ti Olódùmarè

Olódùmarè Asé.


Tradução:

Yemonjá eu te saúdo

Ouça meu clamor,

Você quem dará filhos para quem quer,

Por favor me dê filhos,

Me torna próspero,

Yemonjá, mãe dos peixes me proteja com a sua proteção,

Para que a morte e doenças não entre na minha casa.

Minha mãe, favor torne os meus choros e sofrimentos em alegrias.

Asé do Senhor Supremo

Benção do Senhor Supremo.

97 visualizações0 comentário

Posts recentes

Ver tudo

Oríkí Osanyin

Agbénigi, òròmodìe abìdi sónsó Esinsin abedo kínníkínni; Kòògo egbòrò irín Aképè nigbà òràn kò sunwòn Tíotio tin, ó gbà aso òkùnrùn ta...

Oríkí Obàtálá

Iba òrìsà-nlá Oseremagbo Òrìsà-nla, òrìsà-nia, oba patapata Tu ba won gbe ni ode Iranje, Òrìsà-nla, ogirigbanigbo, alaye ti won...

Oríkí Òrúnmìlà

IBA ÒRÚNMÌLÀ ÒRÚNMÌLÀ IBA O O, ÒRÚNMÌLÀ, ELERI IPIN, AJEJU OOGUN, ADUNDUN LAWO, IFÁ MO PE, ELA MO PE, IFÁ, SOWO DEERE GBOBI RE, IYEROSUN...

Comentários


bottom of page