top of page

Oríkí Ibejì

Atualizado: 27 de out. de 2022

ÒRÌSÀ IBEJÌ

IBA ÒRÌSÀ

ÒRÌSÀ IBEJÌ

DAKUN DABO, MA JEKI A RI IKU OMODE,

MA JEKI A RI IKU AGBA,

ENITI O BI, MAA JEKI O SOKUN,

MAA JEKI A KU IKU AIROTELE,

FUN MI LOWO LATI SE NKAN GBOGBO,

IWO TI O SO ALAKISA DI ALASO, JOWO SO AKISA MI DI ASO,

IWO TO TI ESSE MEJEJI BE SILE ALAKISA, JOWO BE SILE MI,

ÒRÌSÀ IBEJÌ, PELE O,

EJIRE ARA ISOKUN,

JOWO SO MI DI OLORO.SE OLÓDÙMARÈ

OLÓDÙMARÈ ASÉ.


Tradução:

Òrìsà de Ibejì eu te saúdo.

Favor, não deixe acontecer as mortes das crianças,

Não deixe acontecer a morte dos adultos,

Quem tem para não chorar.

Não deixe acontecer a morte imprevista,

Me dê dinheiro para minhas necessidades.

Você que torna pobre o rico favor me torne rico.

Você que entrou na casa do pobre, favor entre na minha casa,

Òrìsà Ibejì, eu te saúdo,

Ejire de Isokun,

Favor tornar-me próspero.

Asé do Senhor Supremo.

Benção do Senhor Supremo.



128 visualizações0 comentário

Posts recentes

Ver tudo

Oríkí Osanyin

Agbénigi, òròmodìe abìdi sónsó Esinsin abedo kínníkínni; Kòògo egbòrò irín Aképè nigbà òràn kò sunwòn Tíotio tin, ó gbà aso òkùnrùn ta...

Oríkí Obàtálá

Iba òrìsà-nlá Oseremagbo Òrìsà-nla, òrìsà-nia, oba patapata Tu ba won gbe ni ode Iranje, Òrìsà-nla, ogirigbanigbo, alaye ti won...

Oríkí Òrúnmìlà

IBA ÒRÚNMÌLÀ ÒRÚNMÌLÀ IBA O O, ÒRÚNMÌLÀ, ELERI IPIN, AJEJU OOGUN, ADUNDUN LAWO, IFÁ MO PE, ELA MO PE, IFÁ, SOWO DEERE GBOBI RE, IYEROSUN...

Comments


bottom of page