Bàbáláwo Ifádárà Amósùn1 de set. de 2021Oríkí AjèAje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di...
Bàbáláwo Ifádárà Amósùn29 de ago. de 2021Oríkí OsanyinAgbénigi, òròmodìe abìdi sónsó Esinsin abedo kínníkínni; Kòògo egbòrò irín Aképè nigbà òràn kò sunwòn Tíotio tin, ó gbà aso òkùnrùn ta...
Bàbáláwo Ifádárà Amósùn29 de ago. de 2021Oríkí ObàtáláIba òrìsà-nlá Oseremagbo Òrìsà-nla, òrìsà-nia, oba patapata Tu ba won gbe ni ode Iranje, Òrìsà-nla, ogirigbanigbo, alaye ti won...
Bàbáláwo Ifádárà Amósùn29 de ago. de 2021Oríkí ÒrúnmìlàIBA ÒRÚNMÌLÀ ÒRÚNMÌLÀ IBA O O, ÒRÚNMÌLÀ, ELERI IPIN, AJEJU OOGUN, ADUNDUN LAWO, IFÁ MO PE, ELA MO PE, IFÁ, SOWO DEERE GBOBI RE, IYEROSUN...
Bàbáláwo Ifádárà Amósùn29 de ago. de 2021Oríkí EgungunIba Egungun Ile Ile Mope O O, Akisale Mo Pe O O, Etigbure Mo Pe O O, Asa Mo Pe O O, Eti Were Ni Ti Ekute Ile, Asunmaparada Ni Tigi Aja...
Bàbáláwo Ifádárà Amósùn29 de ago. de 2021Oríkí IbejìÒRÌSÀ IBEJÌ IBA ÒRÌSÀ ÒRÌSÀ IBEJÌ DAKUN DABO, MA JEKI A RI IKU OMODE, MA JEKI A RI IKU AGBA, ENITI O BI, MAA JEKI O SOKUN, MAA JEKI A KU...
Bàbáláwo Ifádárà Amósùn29 de ago. de 2021Oríkí YemonjáIba Yeye Omo Eja Yemonja Ooo, Wa Gbo Ebe Mi, Iwo Ti Nfun Eniti Nwa Omo Ni Omo, Jowo Mo Pe O, Fun Mi Ni Omo, So Mi Di Oloro, Yomonjá, Yeye...
Bàbáláwo Ifádárà Amósùn29 de ago. de 2021Oríkí IbejiOríkí fún Ibeji B'eji B'eji're B'eji B'eji'la B'eji B'ejiwo Ìba omo ire Àse. Tradução: Dar a luz aos gêmeos traz fortuna boa Dar a luz...